Web3 Yoruba Profile
Web3 Yoruba

@Web3yorubas

Followers
42
Following
78
Media
6
Statuses
42

Àjọṣepọ̀ Web3 Yorùbá àkọ́kọ́. (The first Web3 Yoruba community)

Nigeria
Joined July 2025
Don't wanna be here? Send us removal request.
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
4 days
Ẹ ṣéun fún gbogbo àwon tí wọ́n darapọ̀ mọ́ wa lori eto loni. We rugged and it's already late to continue the space, we'll continue next week with full force and l hope we enjoyed our stay on the space. Till next week 🎙️!
0
0
2
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
4 days
Èyin tèmi a tún ti de loo! Set a reminder for our upcoming space tonight! ⏳ Turn on notifications so you don’t miss out ⏰. Ótun ma rúgógó! 😂☺️ Web3Yoruba gbogbowa lani! Màá rí yín laipẹ́ 🎙️
Tweet media one
1
5
12
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
11 days
0
0
4
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
11 days
0
0
3
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
11 days
14
2
17
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
11 days
Èyin tèmi a tún gbedé oo! 👴🏽 Set a reminder for our upcoming space tonight! Turn on notifications so you don’t miss out. Ótun ma rúgógó 😂 Web3Yoruba gbogbowa lani! Màá rí yín laipẹ́ 🎙️⏳ https://t.co/FTWSnzjSIJ
Tweet media one
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
11 days
Set a reminder for my upcoming Space!
1
4
12
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
11 days
Set a reminder for my upcoming Space!
0
0
2
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
18 days
4
3
12
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
18 days
4
3
12
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
18 days
“Ilé ìṣè ìfowópamọ́ tàbí Bitcoin” "Bank vs Bitcoin" (#Bitcoin or #Bank – Which one do you prefer?) Set a reminder for our upcoming Space!⏳ Turn on notifications so you don’t miss out. Òma rùgògò 😂 Web3Yoruba gbogbowa lani! Òdalè ooo 🎙️ https://t.co/Zx7ckra66u
Tweet media one
1
8
17
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
25 days
@adewaleflex @MubbyOlu @web3_Johnny Ẹ pín wọn pẹ̀lú wa láti fi ìdí ìpìlẹ̀ agbára ìdàgbàsókè agbègbè wa múlẹ̀. Web3Yoruba, gbogbo wa l’ání! Web3Yoruba ti gbogbo wa ni ooooo!!
0
0
5
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
25 days
@adewaleflex @MubbyOlu @web3_Johnny A ní láti dáwọ́ dúró díẹ̀ láti wá àwọn ọ̀nà tí ó ṣiṣẹ́ àti ìlànà tó dáa jù láti bójú tó. Nítorí èyí, a máa padà wá ní ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀ pẹ̀lú àwọn ìpàdé wa tí ó ní ìtùnú àti ìmísí! Títí di ìgbà yẹn, ẹ jẹ́ kí àwọn ìmọ̀ràn àti ìmọ̀ tí ó lè mú ìdàgbàsókè ba ìwùjó wa!
0
0
5
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
25 days
Ẹ káàlé o, ẹyin èyàn wa gbogbo! A ní ìrètí pé a ti lo àǹfààní fun ìtèsíwájú, a pín ìmọ̀, a sì fi ohun rere kún ìrírí wa lónìí. Láti lè ní àwọn ìpàdé wa lóri X 'Web3Yoruba' tí yóò ṣe àṣeyọrí àti tí yóò máa dùn mọ́ni moin!
Tweet media one
2
0
8
@Web3yorubas
Web3 Yoruba
1 month
Bitcoin, Ethereum àti àwọn owó àkọ́sọ – Kí ni wọ́n túmọ̀ sí fún awa #yoruba? (#Bitcoin, #Ethereum & #Crypto – What do they mean for us as Yoruba people?) @MubbyOlu @adewaleflex @Web3Ozzie Set a reminder for my upcoming Space!
1
3
15