Pst Popoola Michael
@Pst_popoola
Followers
156
Following
15
Media
79
Statuses
123
Adura owuro kukutu ti oni,8TH JUNE,2025 Ni oruko ti Jesu,akosile ibi wo ni awon agbara okunkun ti ko nipa re tabi nipa mi ninu ose titun yii,pe dandan o gbodo sele ni,Bayi ni Oluwa Olorun awon omo ogun wi owo ti o ko akosile naa ati iwe ti a ko si Oluwa Olorun awon omo ogun da
0
0
0
Adura owuro kukutu ti oni,22ND MAY,2025 Ni oruko ti Jesu, gbogbo awon ota ti won duro pe a fi dandan ti awon ba ba aye re je,Bayi ni Oluwa Olorun awon omo ogun wi,ki won fi owo ara won se ara won ki ile oni o to su.
0
0
0
Adura owuro kukutu ti oni,9TH MAY,2025 Ni oruko ti Jesu,Bayi ni Oluwa Olorun awon omo ogun wi,oni ku saju ogo re Ni oruko ti Jesu,Bayi ni Oluwa Olorun awon omo ogun wi,ala ibi yen ko ni se ni ori re
0
0
1
Adura owuro kukutu ti oni,25TH April,2025 Ni oruko ti Jesu,Bayi ni Oluwa Olorun awon omo ogun wi,ota ko ta ti o le ma gbe owo kowo nitori re tabi nitori mi ori ara won ni ki won fi gbe.
0
0
0
Adura owuro kukutu ti oni,21ST MARCH,2025 Ni oruko ti Jesu,Bayi ni Oluwa Olorun awon omo ogun wi,Iwo naa a rerin,erin ayo erin idunnu,beni ota re koni so erin naa di ekun mo o lowo,bi Oluwa ti nbe ti emi si wa.amin ooooooooo Jesu
0
0
0
Adura owuro kukutu ti oni,4TH MARCH,2025 Adura igbagbo Ni oruko ti Jesu,Bayi ni Oluwa Olorun awon omo ogun wi,Ki ile oni o to su o ri iyanu nla eyii ti awon ota re papa yoo ba o dupe lelori.
0
0
0
God bless you all Happy weekend all Good morning all
1
0
1
Adura owuro kukutu ti oni,22ND February,2025 Ni oruko ti Jesu, awon okan wo ni won nfi oju rerin si o, sugbon ti won nfi inu ati okan won ba o ja,Bayi ni Oluwa Olorun awon omo ogun wi, Oluwa da ina ogun si won lara, ki won le mo pe oni agbejoro ti oni agbara.
0
0
0
Adura owuro kukutu ti oni,18TH October,2024 Ni oruko ti Jesu,ekun kekun, ibanuje ki ibanuje,isoro ki isoro, idamu ki idamu,ati ohun ti ki fini funni ifokanbale ti o le ku ninu odun,2024 yii Bayi ni Oluwa Olorun awon omo ogun wi emi ati eyin koni kan wa.amin
0
0
0
Adura owuro kukutu ti, 27th July, 2024 Ni oruko ti Jesu, Mo palase gegebi iranse Olorun alaaye, awon ota idile re ati ota ode Olorun alaaye koni fun won ni aye lati gbin ikoro sinu aye re, eyii ti o le ma gba omije ni oju re, ti a ba si ri eyikeyi ti awon ota ti gbin nigbati o su
0
0
1
Adura owuro kukutu ti oni, 18TH JULY, 2024 Ni oruko ti Jesu, Tani eda naa ti nwa ona ifarapa fun lodo olore ati alanu re, iru eni naa ki o gba ida iku ojiji lati odo awon ogun oorun.
0
0
0
Adura owuro kukutu ti oni,16TH JULY, 2024 1)Ni oruko ti Jesu, Mo wi gegebi iranse Olorun alaaye, Oluwa ko fi emi re le awon eni ika eda lowo, ti won fi se aye re bi o ti wu won 2) Ni oruko ti Jesu,gbo iwo ni o ri eyin awon ota re,awon ota re won ni le bori re
0
0
0