
Mr Tom
@IamTommivill
Followers
25K
Following
311K
Media
4K
Statuses
138K
🔲Humanity Preacher 🔲Award Winning #YorubaProverbs Professor 🔲Hospitality 🔲90% Yoruba Contents 🔳 Akọ́mọlédè DM for Ads / PR
Ilẹ̀ Káàárọ̀-Ojíire
Joined February 2014
When Yoruba says "Omi ti ẹ̀yìn wọ̀gbín" Can you tell us what it means? #ÀkànlòÈdèYorùbá
6
1
6
Ẹ kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí 🎂🎊🎊 Èjìrẹ́ ẹdúnjọbí Ire owó, ọlá, àlàáfíà àti àìkú baálè ọrọ̀ fun yín ní àṣẹ Ọlọ́run.
0
0
3
Good Morning Amazing People! Greet me back and have a good day.
58
44
90
Aláàánú láti Gúsù Aláàánú láti Àríwá Aláàánú láti Ìwọ̀-oòruǹ Aláàánú láti Ìlà-oòruǹ Aláàánú ni arìn gbùngbùn Gbogbo wọn á fí àánú àti ìrànlọ́wọ́ ńlá wá èmi àti ìwọ rí ní áìpẹ́ 🤲🏽
35
27
86
O'tafa s'oke, ó yí odo b'ori, bí ọba ayé ó rí ọ, t'orun ń wo óò #yorubaproverbs
Dear Yoruba intellectuals, study these pictures carefully and tell us the Yoruba Proverb without cheating. Add #YorubaProverbs to your comment & repost.
1
1
6
I am now on Facebook sharing our usual Yoruba contents. Follow or be my friend on Facebook
facebook.com
Oladimeji Tommivill. 80 likes · 97 talking about this. 🔳Humanity Preacher 🔳A Melomanic 🔳#YorubaProverbs Prof 🔳Anointed Entertainer 🔳 Contents Creator
3
3
15
Dear Yoruba intellectuals, study these pictures carefully and tell us the Yoruba Proverb without cheating. Add #YorubaProverbs to your comment & repost.
67
41
340
Why are these Club Football teams announcing updating their Bio up and down on TL?
0
0
2
Ayọ̀ ńbọ̀ Ìrọ̀rùn á dé Ìfọ̀kànbalẹ̀ á dé Ògo á tàn Ìmọ́lẹ̀ á tàn Kòní sí ìjakulẹ̀ mọ́ Èyí ni àdúrà mi sí ọ lónìí
22
20
77
Gbogbo Ìgbìyànjú èmi àti ìwọ láti jẹ́ ènìyàn láwùjọ kòní jásí asán ní àṣẹ Ọló̩run 🤲🏾
49
44
166
Ẹ kú Ojúmó̩ ẹ̀yin ò̩rẹ́ ọ̀gbẹ̀ni Tó̩mù Ọ̀sẹ̀ yìí á ṣo èṣo rere fún èmi àti ìwọ
19
8
64
Good Morning friends of Mr Tom. I pray this week favour you & I 🤲🏾
12
2
38