blockchain_in_yoruba
@dyorubaWeb3Girl
Followers
22
Following
162
Media
12
Statuses
92
Mo ń kọ́ Blockchain àti Web3 ní èdè Yorùbá – easy-to-understand knowledge for everyone interested in future money. #Web3 #YorubaTech
Nigeria
Joined September 2025
Kí ni Blockchain gangan? 🤔 A ti ma n gbo orúkọ rẹ lọ́pọ̀, ṣùgbọ́n ṣé o mọ ohun tí ó túmọ̀ sí gangan? Ẹ jẹ́ ká tú u sílẹ̀ ní èdè Yorùbá 🇳🇬✨ #Blockchain #Web3InYoruba #CryptoEducation #BlockchainSimplified #LearnWeb3 #YorubaTech #CryptoNigeria
0
2
7
DEX jẹ́ ibi tí o ti lè ṣe rà, tà, tàbí yí owó crypto padà láì fi agbára fún ẹnikẹ́ni, iwo ló ní akóso patapata. Mo fọ ọ́ sílẹ̀ ní èdè Yorùbá kí gbogbo ènìyàn lè lóye Web3 dáadáa. Ẹ wò ó ní isalẹ 👇 #Web3Yoruba #DEX #CryptoNiYoruba #wallet #BlockchainYoruba #DeFi
0
0
0
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ro pé wallet = exchange… Ṣùgbọ́n iyatọ̀ wa! Ẹ kọ ẹ̀kọ́ nípa CEX vs Wallet nínú fidio mi tuntun. #BlockchainInYoruba #Web3 #CryptoNigeria #CEX #Wallet #CryptoEducation #LearnCrypto #Yoruba
0
2
4
5️⃣ zkSync Name Service (zkNS) O lè ní .zksync orúkọ wallet tirẹ. Fun branding + identity lórí zkSync. Identity se pataki gidi ní Web3. #zkNS #zkSyncNames #Web3Identity
0
0
1
4️⃣ PancakeSwap (zkSync version) Bẹ́ẹ̀ni, PancakeSwap wà lórí zkSync pẹ̀lú! → Swap → Earn → Liquidity Fun àwọn tó mọ̀ ọ́ láti BNB Chain — rọrùn lati lo. #PancakeSwap #PancakeSwapZkSync #zkSync
0
0
2
2️⃣ zkSync Bridge: Lati wá sí zkSync Bí o ṣe fẹ́ bẹ̀rẹ̀, o ní láti bridge ETH sí zkSync. Èyí ló jẹ́ kí o lè lo gbogbo dApps lórí L2 náà. #zkSyncBridge #BridgeTozkSync #zkSync
0
0
3
1️⃣ SyncSwap: Fun Swap rọrùn SyncSwap ni DEX tí ó rọrùn gan-an. → Swap token → Low fees → Beginner-friendly Báwo ni? So wallet, yan token, swap ni kó tan. #SyncSwap #zkSync #zkEcosystem
0
0
2
🧵Top 5 dApps tí o lè lo lórí zkSync (Ọ̀nà rọrùn fún alakọ́bẹrẹ) Lónìí, ẹ jẹ́ ká wo 5 dApps tó wúlò gan-an lórí zkSync, àwọn tí o lè lo fún swap, bridging, staking àti ìbẹ̀rẹ̀ Web3. #zkSync #SyncSwap #zkEVM #Layer2 #Web3inYoruba #YorubaCrypto #CryptoNigeria #DYORUBA
5
1
2
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ro pé wallet = exchange… Ṣùgbọ́n iyatọ̀ wa! Ẹ kọ ẹ̀kọ́ nípa CEX vs Wallet nínú fidio mi tuntun. #BlockchainInYoruba #Web3 #CryptoNigeria #CEX #Wallet #CryptoEducation #LearnCrypto #Yoruba
0
2
4
🧵Kí ni zkSync? Ìtumọ̀ rọrùn ní Yorùbá zkSync jẹ́ Layer 2 lórí Ethereum tí ó jẹ́ kó rọrùn kí a ṣe transaction kíakia, ní owó kékeré, láì fi ààbò ṣeré. #zkSync #zkEVM #ZKLayer2 #Web3inYoruba #YorubaCrypto #CryptoNigeria #BlockchainYoruba #DYorubaWeb3Girl
7
2
7
Pẹ̀lú Braavos àti Argent X, lílo StarkNet rọrùn gan-an. Wallet connect → Ṣe swap → Lo dApps gbogbo rẹ̀ ní owó kékeré. Ní kókó, StarkNet kì í ṣe L2 lasan, ó jẹ́ ìmọ̀ tó lé e lórí cryptography àti scaling. Èyí ló yà á sílẹ̀ gan-an ní agbègbè Web3.
0
0
3
Ó dá lórí Cairo, èdè tó jẹ́ kí smart contracts rẹ̀ yara, scalable, tí ó sì lè ṣe iṣẹ́ tó tóbi ju L1 lọ. Eyi ló jẹ́ kí StarkNet ṣe amúlò tí ó jinlẹ̀
0
0
3
StarkNet tún jẹ́ general-purpose ó lè gbe gbogbo irú app bi DeFi, gaming, identity, AI, zk-apps, gbogbo rẹ̀.
0
0
3
Díẹ̀ lára L2 míì lo zk-SNARKs, ṣùgbọ́n StarkNet n lo STARKs , tí kò nílò trusted setup, tí ó sì jẹ́ kíkáàbò pátápátá. ✅No setup. ✅More transparent.
0
0
3
🧵 Kí ló yà StarkNet sílẹ̀ kúrò ní gbogbo L2 míì? Lára gbogbo Layer 2 lórí Ethereum, StarkNet ní ìmọ̀ tó yàtọ̀ sí gbogbo ẹlòmíì, ó lo STARK proofs, ẹ̀rọ cryptography tó ní ààbò tó ga gan #StarkNet #YorubaCrypto #Web3Nigeria #Web3inYoruba #BlockchainYoruba #CryptoEducation
4
0
3
Níparí, zkSync jẹ́ ọ̀nà tí Ethereum fi ń di kíakia, olówó poku, tí ó sì jẹ́ kó lè dé ọdọ gbogbo ènìyàn. Ẹ jẹ́ ká tẹ̀síwájú sí ilé iṣẹ́ Web3 ní èdè wa.
0
0
3
Ta ni ó lè lo? Gbogbo ọmọ Yorùbá tí wọ́n bá ní wallet bíi MetaMask, OKX, tàbí Rabby. O kan bridge, o sì bẹ̀rẹ̀ sí í lo. Rọrùn gidi.
0
0
3
Kí ló fà kí zkSync ṣe pàtàkì? O dín congestion kù lórí Ethereum, ó sì jẹ́ kí transaction jẹ́ kíakia + din owó. Ẹ̀rọ tó dá lórí cryptography to dájú.
0
0
4
zkSync mú kí Web3 lè ṣiṣẹ́ dáadáa fún gbogbo ènìyàn. ká lè san owó, ṣe swap, tàbí lo dApp, láì dúró pẹ́ àti láì san gas tó ga.
0
0
2
Orúkọ “zk” túmọ̀ sí Zero-Knowledge. Ìtúmọ̀ rèẹ̀ ni pé o lè jẹ́risi transaction láì fi gbogbo ohun tí o ṣe hàn. Ààbò tó pọ̀ sí i.
0
0
3